Ísíkẹ́lì 12:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ọmọ ènìyàn, jẹ oúnjẹ rẹ̀ pẹ̀lú ẹ̀gbọ̀n rìrì, sì mu omi rẹ pẹ̀lú ìwárìrì àti àìbalẹ̀ àyà.

Ísíkẹ́lì 12

Ísíkẹ́lì 12:16-20