Ísíkẹ́lì 12:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Wọn ó sì mọ̀ pé èmi ni Olúwa láàrin àwọn orílẹ̀ èdè, tí mo bá tú wọn ká láàrin àwọn orílẹ̀ èdè, tí mo sì fọ́n wọn ká sí ilẹ̀ káàkiri.

Ísíkẹ́lì 12

Ísíkẹ́lì 12:9-16