Ísíkẹ́lì 11:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Torí náà, báyìí ni Olúwa Ọlọ́run wí, àwọn òkú tí ẹ pa sáàrin yín ni ẹran, ìlú yìí sì ni ìkòkò ìdáná ṣùgbọ́n n ó le yín jáde níbẹ̀.

Ísíkẹ́lì 11

Ísíkẹ́lì 11:1-11