Ísíkẹ́lì 11:23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ògo Olúwa sì gòkè lọ kúrò láàrin ìlú, ó sì dúró lórí òkè tó wà ní ìlà oòrùn ìlú náà.

Ísíkẹ́lì 11

Ísíkẹ́lì 11:21-25