Ísíkẹ́lì 11:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Nítorí náà, sọ pé: ‘Báyìí ni Olúwa Ọlọ́run wí: Èmi yóò kó wọn jọ kúrò láàrin àwọn orílẹ̀ èdè tí mo fọ́n wọn ká sí, Èmi yóò sì fún wọn ní ilẹ̀ Ísírẹ́lì padà.’

Ísíkẹ́lì 11

Ísíkẹ́lì 11:15-21