Ísíkẹ́lì 11:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí mo ṣe ń sọtẹ́lẹ̀ lọ́wọ́, Pélátíà ọmọ Bénáyà kú. Mo sì dojúbolẹ̀, mo sì kígbe sókè pé, “Áà! Olúwa, Ọlọ́run! Ṣé o fẹ́ pa ìyókù Ísírẹ́lì run pátapáta ni?”

Ísíkẹ́lì 11

Ísíkẹ́lì 11:5-16