Ísíkẹ́lì 10:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àfiwé ojú àti ìrísí wọn rí bákan náà pẹ̀lú àwọn tí mo rí létí odò kébárì. Olúkúlùkù wọn sì ń lọ sí ọ̀kánkán tààrà.

Ísíkẹ́lì 10

Ísíkẹ́lì 10:18-22