Ísíkẹ́lì 1:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní abẹ́ ìyẹ́ wọn ní ẹ̀gbẹ́ mẹ́rẹ̀ẹ̀rin wọn ní ọwọ́ ènìyàn. Gbogbo àwọn mẹ́rẹ̀ẹ̀rin ní ojú àti àwọn ìyẹ́,

Ísíkẹ́lì 1

Ísíkẹ́lì 1:1-17