Ísíkẹ́lì 1:25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí wọ́n ṣe dúró tí wọ́n sì rẹ ìyẹ́ wọn sílẹ̀, ohùn kan jáde láti inú òfuurufú tó rán bò wọ́n.

Ísíkẹ́lì 1

Ísíkẹ́lì 1:23-28