Ísíkẹ́lì 1:23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìyẹ́ wọn sì ń kan ara wọn lábẹ́ òfuurufú yìí, ọ̀kọ̀ọ̀kan wọn sì ní ìyẹ́ méjì méjì tó bo ara wọn.

Ísíkẹ́lì 1

Ísíkẹ́lì 1:15-24