Ísíkẹ́lì 1:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí àwọ́n ẹ̀dá bá ń rìn, kẹ̀kẹ́ ẹgbẹ wọn náà yóò rìn, bí wọ́n fò sókè, kẹ̀kẹ́ náà yóò fò sókè.

Ísíkẹ́lì 1

Ísíkẹ́lì 1:18-23