Ísíkẹ́lì 1:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn kẹ̀kẹ́ yìí ń yí bí wọ́n ti ń yí, wọ́n ń lọ tààrà síbi tí ọ̀kọ̀ọ̀kan àwọn ẹ̀dá alààyè kọjú sí, kẹ̀kẹ́ wọn kò sì yapa bí àwọn ẹ̀dá náà ti n lọ.

Ísíkẹ́lì 1

Ísíkẹ́lì 1:16-26