Ísíkẹ́lì 1:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olúkúlùkù wọn ń lọ tààrà. Níbikíbi tí èmi bá ń lọ, ni àwọn náà ń lọ, láì wẹ̀yìn bí wọ́n ti ń lọ.

Ísíkẹ́lì 1

Ísíkẹ́lì 1:2-14