Ìfihàn 9:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìrísí àwọn eṣú náà sì dàbí àwọn ẹṣin tí a múra sílẹ̀ fún ogun; àti ní orí wọn ni ohun tí o dàbí àwọn adé wúrà wà, ojú wọn sì dàbí ojú ènìyàn;

Ìfihàn 9

Ìfihàn 9:1-10