Ìfihàn 9:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

A sì pàṣẹ fún wọn pé, kí wọn má ṣe pa wọ́n, ṣùgbọ́n kí a dá wọn ni oró ni oṣù marùn-ún: oró wọn sì dàbí oró àkéekèe, nígbà tí o bá ta ènìyàn.

Ìfihàn 9

Ìfihàn 9:1-8