Ìfihàn 9:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nípa ìyọnu mẹ́ta wọ̀nyí ni a tí pa ìdámẹ̀ta ènìyàn, nípa iná, àti nípa èéfín, àti nípa súfúrù tí o ń tí ẹnu wọn jáde.

Ìfihàn 9

Ìfihàn 9:9-21