Ìfihàn 9:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

A sì tú àwọn ańgẹ́lì mẹ́rin náà sílẹ̀, tí a ti pèṣè tẹ́lẹ̀ fún wákàtí náà, àti ọjọ́ náà, àtí oṣù náà, àti ọdún náà, láti pa ìdámẹ̀ta ènìyàn.

Ìfihàn 9

Ìfihàn 9:8-16