Ìfihàn 8:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èkínní sì fọn ìpè tirẹ̀: Yìnyín àti iná, tí o dàpọ̀ pẹ̀lú ẹ̀jẹ̀, sì jáde, a sì dà wọ́n sórí ilẹ̀ ayé: ìdámẹ̀ta ilẹ̀ ayé si jóná, ìdámẹ̀ta àwọn igi sì jóná, àti gbogbo koríko tútù sì jónà.

Ìfihàn 8

Ìfihàn 8:4-13