Ìfihàn 8:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

A sì ń pe orúkọ ìràwọ̀ náà ni ìwọ̀, ìdámẹ̀ta àwọn omi sì di ìwọ̀, ọ̀pọ̀lọ́pọ̀ ènìyàn sì tí ipa àwọn omi náà kú, nítorí tí a sọ wọn di kíkorò.

Ìfihàn 8

Ìfihàn 8:5-13