Ìfihàn 7:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí òdọ̀-Àgùntàn tí ń bẹ ni àárin ìtẹ́ náà ni yóò máa ṣe Olùṣọ́-Àgùntàn wọn,tí yóò sì máa ṣe amọ̀nà wọn sí ibi orísun omi ìyè:Ọlọ́run yóò sì nu omijé gbogbo nù kúrò ni ojú wọn.”

Ìfihàn 7

Ìfihàn 7:12-17