Ìfihàn 7:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí náà ni,“wọn ṣe ń bẹ níwájú ìtẹ́ Ọlọ́run,tí wọn sì ń sìn ín, lọ́sàn àti lóru nínú tẹḿpílì rẹ̀;ẹni tí o jókòó lórí ìtẹ́ náà yóò si ṣíji bò wọn.

Ìfihàn 7

Ìfihàn 7:10-16