Ìfihàn 6:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹṣin mìíràn tí ó pupa sì jáde: a sì fi agbára fún ẹni tí ó jókòó lórí rẹ̀, láti gba àlàáfíà kúrò lórí ilẹ̀ ayé, àti pé kí wọn kí ó máa pa ara wọn: A sì fi idà ńlá kan lé e lọ́wọ́.

Ìfihàn 6

Ìfihàn 6:1-7