Ìfihàn 5:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mo sì rí i ni ọwọ́ ọ̀tún ẹni tí ó jókòó lórí ìtẹ́ náà, ìwé kan ti a kọ nínú àti lẹ̀yìn, ti a sì fi èdìdì méje dí.

Ìfihàn 5

Ìfihàn 5:1-2