Ìfihàn 4:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Yíká ìtẹ́ náà sì ni ìtẹ́ mẹ́rínlélógún; àti lórí àwọn ìtẹ́ náà mo rí àwọn àgbà mẹ́rìnlélógún jókòó, tí a wọ̀ ni aṣọ àlà; adé wúrà sì wà ni orí wọn.

Ìfihàn 4

Ìfihàn 4:1-11