Ìfihàn 22:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Òru kì yóò sí mọ́; wọn kò sì ní wa ìmọ́lè fìtílà, tàbí ìmọ́lẹ̀ oòrùn; nítorí pé Olúwa Ọlọ́run ni yóò tan ìmọ́lẹ̀ fún wọn: wọn ó sì máa jọba láé àti láéláé.

Ìfihàn 22

Ìfihàn 22:1-10