Ìfihàn 22:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi kìlọ̀ fún olúkúlùkú ẹni tó ń gbọ́ ọ̀rọ̀ ìsọtẹ́lẹ̀ inú ìwé yìí pé, bí ẹnikẹ́ni ba fi kún wọn, Ọlọ́run yóò fí kún àwọn ìyọnu tí a kọ sínú ìwé yìí fún un.

Ìfihàn 22

Ìfihàn 22:11-21