Ìfihàn 22:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Èmi, Jésù, ni ó rán ańgẹ́lì mi láti jẹ̀rìí nǹkan wọ̀nyí fún yin ní tí àwọn ìjọ. Èmi ni gbòngbò àti irú-ọmọ Dáfídì, àti ìràwọ̀ òwúrọ̀ tí ń tàn.”

Ìfihàn 22

Ìfihàn 22:10-18