Ìfihàn 22:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Kíyèsí i, èmi ń bọ̀ kánkán; èrè mí sì ń bẹ pẹ̀lú mi, láti sán fún olúkúlùkù gẹ́gẹ́ bí iṣẹ́ rẹ̀ yóò tí rí.

Ìfihàn 22

Ìfihàn 22:8-17