Ìfihàn 21:27 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ohun aláìmọ́ kan ki yóò sì wọ inú rẹ̀ rárá, tàbí ohun tí ń ṣiṣẹ́ ìríra àti èké; bí kò ṣe àwọn tí a kọ sínú ìwé ìyè Ọ̀dọ́-Àgùntàn.

Ìfihàn 21

Ìfihàn 21:19-27