Ìfihàn 21:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

A sì fi Jásípérì mọ odi ìlú náà. Ìlú náà sì jẹ́ kìkì wúrà, ó dàbí dígí tí o mọ́ kedere.

Ìfihàn 21

Ìfihàn 21:11-19