Ìfihàn 21:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Odi ìlú náà sì ni ìpìlẹ̀ méjìlá, àti lórí wọn orúkọ àwọn Àpósítélì méjìlá tí Ọ̀dọ́-Àgùntàn.

Ìfihàn 21

Ìfihàn 21:5-17