Ìfihàn 21:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mo sì rí ọ̀run titun kan àti ayé titun kan: nítorí pé ọ̀run ti ìṣáajú àti ayé ìṣáajú ti kọjá lọ; òkun kò sì sí mọ́.

Ìfihàn 21

Ìfihàn 21:1-7