Ìfihàn 20:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

O sì di Dírágónì náà mú, ejò àtijọ́ nì, tí í ṣe èṣù, àti Sàtánì, ó sì dè é ní ẹgbẹ̀rún ọdún.

Ìfihàn 20

Ìfihàn 20:1-7