Ìfihàn 20:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Òkun sì jọ̀wọ́ àwọn òkú tí ń bẹ nínú rẹ̀ lọ́wọ́; àti òkú àti ipò-òkú sì jọ̀wọ́ òkú tí ó wà nínú wọn pẹ̀lú: a sì ṣe ìdájọ́ wọn, olúkúlùkù gẹ́gẹ́ bí iṣẹ́ wọn.

Ìfihàn 20

Ìfihàn 20:10-15