Ìfihàn 20:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

A sì wọ́ Èsù tí ó tàn wọ́n jẹ lọ sínú adágún iná àti súfúrù, níbi tí ẹranko àti wòlíì èké nì gbé wà, a ó sì máa dá wọn lóró tọ̀sán tòru láé àti láéláé.

Ìfihàn 20

Ìfihàn 20:5-15