Ìfihàn 2:23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi o pa àwọn ọmọ rẹ̀; gbogbo ìjọ ni yóò sì mọ̀ pé, èmi ni ẹni tí ń wádìí inú àti ọkàn: èmi ó sì fi fún olúkúlùkù yín gẹ́gẹ́ bí iṣẹ́ rẹ̀.

Ìfihàn 2

Ìfihàn 2:17-29