Ìfihàn 19:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn ìyókù ni a sì fi idà ẹni tí ó jókòó lórí ẹsin náà pa, àní idà tí ó ti ẹnu rẹ̀ jáde: Gbogbo àwọn ẹyẹ sì ti ipa ẹran ara wọn yó.

Ìfihàn 19

Ìfihàn 19:14-21