Ìfihàn 19:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ojú rẹ̀ dàbí ọ̀wọ́ iná, àti ní orí rẹ̀ ni adé púpọ̀ wà; ó sì ní orúkọ kan tí a kọ, tí ẹnikẹ́ni kò mọ́, bí kò ṣe òun tìkárarẹ̀.

Ìfihàn 19

Ìfihàn 19:9-13