Ìfihàn 18:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ańgẹ́lì alágbára kan sì gbé òkúta kan sókè, ó dàbí ọlọ ńlá, ó sì jù ú sínú òkun, wí pé:“Báyìí ní a ó fi agbára ńlábíi Bábílónì ìlú ńlá ni wó,a kì yóò sì rí i mọ́ láé.

Ìfihàn 18

Ìfihàn 18:20-24