Ìfihàn 18:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Àti àwọn èso tí ọkàn rẹ̀ ń ṣe. Ìfẹ́kufẹ̀ẹ́ sí, si lọ kúrò lọ́dọ̀ rẹ, àti ohun gbogbo tí ó dùn tí ó sì dára ṣègbé mọ́ ọ lójú, kì yóò sì tún rí wọn mọ́ láé.

Ìfihàn 18

Ìfihàn 18:4-19