Ìfihàn 17:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ìwo mẹ́wáà tí ìwọ sì rí ni ọba mẹ́wàá ni wọn, tí wọn kò ì ti gba ìjọba; ṣùgbọ́n wọn gba ọlá bí ọba pẹ̀lú ẹranko náà fún wákàtí kan.

Ìfihàn 17

Ìfihàn 17:7-15