Ìfihàn 16:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí ẹ̀mí èṣù ni wọ́n, tí ń ṣe iṣẹ́ ìyanu, àwọn tí ń jáde lọ sọ́dọ̀ àwọn ọba gbogbo ilẹ̀ ayé, láti gbá wọn jọ sí ogun ọjọ́ ńlá Ọlọ́run Olúdàmarè.

Ìfihàn 16

Ìfihàn 16:7-17