Ìfihàn 15:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àti ọ̀kan nínú àwọn ẹ̀dá alààyè mẹ́rin náà fi àgbàda wúrà méje fún àwọn ańgẹ́lì méje náà, tí ó kún fún ìbínú Ọlọ́run, ẹni tí ń bẹ láàyè láé àti láéláé.

Ìfihàn 15

Ìfihàn 15:1-8