Ìfihàn 13:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

A sì fún-un láti máa bá àwọn ènìyàn-mímọ́ jagun, àti láti ṣẹ́gun wọn: a sì fi agbára fún un lórí gbogbo ẹ̀yà, àti ènìyàn, àti èdè, àti orílẹ̀.

Ìfihàn 13

Ìfihàn 13:4-16