Ìfihàn 13:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì ń lo gbogbo agbára ẹranko èkínní níwájú rẹ̀, ó sì mú ilẹ̀ ayé àti àwọn tí ń gbé inú rẹ̀ foríbalẹ̀ fún ẹranko èkínní tí a ti wo ọgbẹ́ àṣápa rẹ̀ sàn.

Ìfihàn 13

Ìfihàn 13:11-18