Ìfihàn 12:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ogun sì ń bẹ ní ọ̀run: Mákẹ́lì àti àwọn ańgẹ́lì rẹ̀ bá dírágónì náà jagun; dírágónì sì jagun àti àwọn angẹ́lì rẹ̀.

Ìfihàn 12

Ìfihàn 12:1-14