Ìfihàn 12:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìrù rẹ̀ sì wọ́ ìdá mẹ́ta àwọn ìràwọ̀, ó sì jù wọ́n sí ilẹ̀ ayé, dírágónì náà sì dúró níwájú obìnrin náà tí ó fẹ́ bímọ, pé nígbà tí o bá bí i, kí òun lè pa ọmọ rẹ̀ jẹ.

Ìfihàn 12

Ìfihàn 12:1-11