Ìfihàn 11:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Òkú wọn yóò sì wà ni ìgboro ìlú ńlá náà tí a ń pè ní Sódómù àti Éjíbítì nípa ti ẹ̀mí, níbi tí a gbé kan Olúwa wọ́n mọ́ àgbélébùú.

Ìfihàn 11

Ìfihàn 11:2-11