Ìfihàn 10:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

A sì wí fún mi pé, “Ìwọ ó sì tún sọ àsọtẹ́lẹ̀ nípa ọ̀pọ̀lọ́pọ̀ ènìyàn, àti orílẹ̀ àti èdè, àti àwọn ọba.”

Ìfihàn 10

Ìfihàn 10:10-11