Ìfihàn 1:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kíyèsí i, Ó ń bọ̀ nínú àwọsánmọ̀;gbogbo ojú ni yóò sì rí i,àti àwọn tí ó gún un ní ọ̀kọ̀ pẹ̀lú;àti gbogbo orílẹ̀-èdè ayé ni yóò sì máa pohùnréré ẹkún nítorí rẹ̀.Bẹ́ẹ̀ náà ni. Àmín.

Ìfihàn 1

Ìfihàn 1:6-11